Home orisiirisii Àwọn ọlọ̀dẹ ní Enugu ti ṣe obìnrin léṣe nítorí ẹgbẹ̀rún naira kan.
orisiirisii - Orisirisi - July 6, 2019

Àwọn ọlọ̀dẹ ní Enugu ti ṣe obìnrin léṣe nítorí ẹgbẹ̀rún naira kan.

Arabinrin omo Naijiria kan ti n je Gift Okoro ti fi esun kan awon olode adugbo re pe won fi iya je oun nitori oun san egberun naura kan ti won bere lowo oun gege bi owo olode.

Gege bi Gift se so, o ni awon olode naa lu oun debi pe oun o le da rin.

Ore re kan ti n je Christian Onwugbolu, ti so isele naa lori Facebook, o si n bere idajo fun ore re, o ni awon olode naa je omo egbe Amorji Nike Neighborhood watch.

O ni: “isele yii se ni Amorji Nike Enugu East local Government Area ni ipinle Enugu. Aworan arabinrin ti e n wo yii n gbe ni agbegbe naa, awon olode Amorji Nike Neighborhood ni won na an nitori ko san egberun kan naira ti o je owo olode.
Nigba ti won lo ba pe kimo san owo olode, o so fun won pe ki won duro ki oun lo mu owo naa wa, amo o ti san owo osu meta siwaju tele, nugba ti o wole lati mu owo naa wa, won sare tele, won si gbe faanu re, nigba ti o bere pe kilode ti won se wu iru iwa naa, won bere si ni naa, won naa debi pe ko le fi ese re rin.

Leyin ti won naa tan, won tun so fun pe ko si nnkan ti o le se. Asilo agbara gbaa ni eyi, ki owo te awon olode naa, won o ni eto lati se obinrin bayii.”

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Arábìnrin ti da omi gbóná lu ọmọ.

Owo olopaati tearabinrin kan ti o da omi gbona lu oju ara omobinrin kekere kan ti n gbe ni…