Home Entertainment Stella Damasus àti ọkọ̀ rẹ̀ Daniel Ademinokan tí ṣàlàyé àwọn nǹkan tí ojú wọn ń rí láti tọ àwọn ọmọ wọn.

Stella Damasus àti ọkọ̀ rẹ̀ Daniel Ademinokan tí ṣàlàyé àwọn nǹkan tí ojú wọn ń rí láti tọ àwọn ọmọ wọn.

Gbajumo onitiata tele, Stella Damasus ati oko re Daniel Adaminokan ti salaye awon nnkan ti oju won n ri lati to awon omo won, Stella ti bimo ninu igbeyawo re tele bee si ni Daniel naa ti bimomri ninu igbeyawo re tele.

Stella ti salaye pe iru ebi ti oun ni gi oun die, o ni nigba miiran oun ma n sora lati ba omo Daniel okunrin ki omo ma dabi ika. O ni nigba to ya ni iya oko oun so fun oun pe ti oun ba nifee omo naa looto pe bi oun ba se n ba awon omo ti e obinrin wi ni ki oun se ma ba omo naa wi.

Daniel ti o salaye pe igbeywa oun tele ni bi o se je, ti ni awon o ki n lo oro iyawo baba tabi oko mama “step” ni ile awon. O ni awon eeyan o ki n gbagbo pe oun ko ni baba awon omo Stella obinrin meji. O ni ipade iyawo oun tele, Doris ati Stella Damasus, o tubo salaye pe ati ni molebi nla kii se nnkan kekere.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Arábìnrin ti da omi gbóná lu ọmọ.

Owo olopaati tearabinrin kan ti o da omi gbona lu oju ara omobinrin kekere kan ti n gbe ni…