Home orisiirisii Olùkó ti fẹ sọ akẹ́kọ̀ọ́ rẹ̀ di afọ́jú.
orisiirisii - Orisirisi - July 5, 2019

Olùkó ti fẹ sọ akẹ́kọ̀ọ́ rẹ̀ di afọ́jú.

Oluko kan ni ile iwe King Abdul’azeez African Institute ni Potiskum, ni ipinle Yobe ti lu akẹ́kọ̀ọ́ re,Ibrahim Muhammad Mai luku, ni SS1 bi eni ma fe e ku, koda bi oju omo naa ko ba fo, bayi bayi ni kju naa yoo ma wo.

Idi ti oluko fi se omo naa bayi o ti di mimo, amo a lero pe won ma mu oluko naa yoo si jiya ese re.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Arábìnrin ti da omi gbóná lu ọmọ.

Owo olopaati tearabinrin kan ti o da omi gbona lu oju ara omobinrin kekere kan ti n gbe ni…