Home iroyin Óga ò! Àwọn géńdé ọkùnrin mẹ́ta fí ipá bá ọmọbìnrin kan lòpọ̀.
iroyin - orisiirisii - Orisirisi - July 5, 2019

Óga ò! Àwọn géńdé ọkùnrin mẹ́ta fí ipá bá ọmọbìnrin kan lòpọ̀.

Awon olopaa ipinle Niger ti munawon okunrin meta ti won n je Abdulrahman Ahmed omo odun mokandinlogun, Isyaku Umar omk odun ogun ati Adamu Sani omo odun ogun fun esun pe won fi ipa ba omo odun merinla lopo ni agbegbe Maitumbi Minna.

Agbenuso awon olopaa ipinle naa, Mohammed Abubakar ni awon okunrin naa ji omo naa gbe nigba ti won ni ise, won si gbs lo si ibi kan, awon meteeta si fi ipa ba lopo. Iroyin isele naa kan si iya omo naa, o si gba ago olopaa lo lati lo fi ejo sun.

Abubakar ni awon okunrin ti jewo ese won, won si ma to fi oju ba ile ejo.

Orisirisi isele ni a ti n gbo nipa ifipabalopo, ki olorun ba wa ko sinu awon okunrin yii , ki won dekun iwa buruku yii.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Arábìnrin ti da omi gbóná lu ọmọ.

Owo olopaati tearabinrin kan ti o da omi gbona lu oju ara omobinrin kekere kan ti n gbe ni…