Home Entertainment Mi ò yan àlè rí – onítíátà aláwàdà, Saka.

Mi ò yan àlè rí – onítíátà aláwàdà, Saka.

Gbajumo onitiata alawada, Hafiz Oyetoro, ti awon eeyan mo si Saka ti ni igbeyawo oun ti pe odun merindinlogun laisi wahala nítorí oun o se agbere tabi yan ale ri ninu igbeyawo naa. Ninu ifoworowanilenuwo ti o ni pelu Punch, Saka ni,

“nnkan ti o dara ju ti o le sele si okunrin ni ki o fe iyawo ti o ni ero kan naa pelu e. Iyawo mi ni ero kan naa pelu mi. A jo ni ero kan naa ero kan naa nipa ile aye, o si ma n fun mi ni aye lati je olori ile. Eyi ti o je koko pataki ni pe lati igba ti mo ti se igbeyawo mi o yan ale ri. Mi o ba obinrin imii ni ibasepo.”

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Arábìnrin ti da omi gbóná lu ọmọ.

Owo olopaati tearabinrin kan ti o da omi gbona lu oju ara omobinrin kekere kan ti n gbe ni…