Home orisiirisii Kàyéfì : Bàbá ń bá ọmọ rẹ̀ ní ìbásepọ̀, o sì ṣe oyún fun.
orisiirisii - Orisirisi - July 5, 2019

Kàyéfì : Bàbá ń bá ọmọ rẹ̀ ní ìbásepọ̀, o sì ṣe oyún fun.

Akarunkin kan ti n je @u6achukwu ti so lori twitter pe molebi oun n ba omo re obinrin ni ibasepo, mama omo naa o si gba omo na gbo, eyin oko re ni o gbe si.

@u6achukwu ni molebi oun ti n je Chimezie, je omo odun metadinlogun, ni baba oun ma n fi ipa ba oun ni asepo lati bii odun meji seyin, oun si ti se oyun meta fun.

Mama oun naa o ni itara abiamo nipa isele naa, o ni iro ni omo oun n pa, eyin oko re ni o gbe si. Bee si ni awon odo ilu ni Ikeduru ni ipinle Imo o ri nkankan se si.

Bayii arakunrin naa n bere idajo fun Chimezie lori Twitter, o si ti bere ipolongo pelu #JusticeFirChimezie.

Eyi tun ba ni leru.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Arábìnrin ti da omi gbóná lu ọmọ.

Owo olopaati tearabinrin kan ti o da omi gbona lu oju ara omobinrin kekere kan ti n gbe ni…