Home iroyin Ademola Adeleke ti pàdánù ipò Gómìnà.

Ademola Adeleke ti pàdánù ipò Gómìnà.

Ile ejo Supreme Court ti ni Gboyega Adetola ni Gomina ti a yan fun ipinle Osun.

Oludije ipo gomina fun egbe oloselu PDP, Ademola Adeleke, ti o je aburo baba gbajumo akorin Davido, ni o pe ejo leyin ibo ti o waye ni September odun 2018, leyin ti o ni esi ti INEC fi lile o te oun lorun. Igbimo naa si ni Adeleke ni o bori ni osu March. Gboyega naa si pada si ile ejo Court of Appeal lati pe ejo.

Ni May, ile ejo appeal da ejo ti o wa ni ojurere oludije egbe oloselu APC. Adeleke naa si pe ejo si ile ejo Supreme court.

Ni aaro oni, márùn-ún ninu awon adajo meje ti won fe da ejo naa da ejo ti o wa ni ojurere Oyetola, ti meji to ku si wa fun Adeleke.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Arábìnrin ti da omi gbóná lu ọmọ.

Owo olopaati tearabinrin kan ti o da omi gbona lu oju ara omobinrin kekere kan ti n gbe ni…