Home iroyin Ọ̀mùtí ti fi ọkọ̀ pa àwọn ọmọ méjì.
iroyin - orisiirisii - Orisirisi - July 4, 2019

Ọ̀mùtí ti fi ọkọ̀ pa àwọn ọmọ méjì.

Arákùnrin kan ti o mu oti yo ti o si n bo kati ile ejo ti fi oko pa awon omo meji ni Ikot Ekpene Road, Akwa Ibom ni aaro kutu ojo Satide ti o koja.

Iroyin ni, awon omo naa je omo odun mesan-an ati omo mejila ti won n bo lati ibi aduro fun oku(wakekeep) iya iya won. Ti won si n se eto ati sin iya naa ni ojo ti isele naa se.

Okan lara awon omo naa ku loju ese ti won si sare gbe ikeji lo si ile iwosan pelu agbara eje, nibi ti o pada ku si.

Won ni awon olopaa ti won wa ni ibi ti isele naa ti se ri oogun lile(cocaine) ati orisirisi oti ninu oko Toyato Rav4 ti o pa awon omo naa.

Lowolowo bayii, a o ti mo boya owo ti te arakunrin ti o huwa buruku yii.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Arábìnrin ti da omi gbóná lu ọmọ.

Owo olopaati tearabinrin kan ti o da omi gbona lu oju ara omobinrin kekere kan ti n gbe ni…