Home iroyin Kọmíṣọ́nà ọlọ́pàá Ìpínlẹ̀ Imo ti bèrè fún àwárí ọlọ́pàá tí ó pa Ikenna Ukachi.
iroyin - orisiirisii - Orisirisi - July 4, 2019

Kọmíṣọ́nà ọlọ́pàá Ìpínlẹ̀ Imo ti bèrè fún àwárí ọlọ́pàá tí ó pa Ikenna Ukachi.

Komisona olopaa ni ipinle Imo, Ogbeni Rabiu Ladofo, ti ni ki won wa Insp. Okwuchukwu Nwanefi ti o pa omo odun marundinlogbon Ikenna Ukachi ni Umuokeh community, Obolo Local Government Area.

Ni ojo Monday ni olopaa naa yin ibon pa arakunrin naa leyin àríyànjiyàn die ti o si salo. Iku arakunrin naa lo faa ti awon odo fi bínú lọ si Obowo Divisional Police Station ti won si dana sun un.

Nigba ti Ladodo n ba awon oniroyin soro ni ojo Wednesday, o ni won ti bere si ni wa olopaa to se ise ibi naa.

O si fi asiko naa so fun olopaa naa pe o ma dara ko fira re sile nibikibi to ba wa nitori owo si ma pada te e.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Arábìnrin ti da omi gbóná lu ọmọ.

Owo olopaati tearabinrin kan ti o da omi gbona lu oju ara omobinrin kekere kan ti n gbe ni…