Ìyá ti fi oògùn p’ẹ̀fọn(sniper) pa ọmọ rẹ̀.
Arakunrin kan @aproko_doctor ti so lori twitter bi iya se fi oogun p’efon si ori omo re lati pa kokoro ti o wa ni ori re, ti o si gba emi omo naa.
O ni “ mo sese gbo itan ti o banileru nipa iya ti o fi oogun p’efon (sniper) si dada ori ori omo re ti o si fi ora bo mo lori nitori o fe pa kokoro. Omo naa ti ku bayii.
Oogun p’efon(sniper) yii je okan lara awon nnkan ti awon oloyinbo n oe ni organophosphates ti o si le wo awo eeyan.
Ki e sora”
Arábìnrin ti da omi gbóná lu ọmọ.
Owo olopaati tearabinrin kan ti o da omi gbona lu oju ara omobinrin kekere kan ti n gbe ni…