Home iroyin Èèyàn méjì ti kú, ọkọ̀ ọgbọ́n sì ti jóná nínú iná tó wáyé ní Ijegun.
iroyin - orisiirisii - Orisirisi - July 4, 2019

Èèyàn méjì ti kú, ọkọ̀ ọgbọ́n sì ti jóná nínú iná tó wáyé ní Ijegun.

Eeyan meji ti salaisi, oko ogbon naa si ti jona ninu opa epo ti o lana ni agbegbe Ijegun ni ipinle Eko ni aaro oni July 4.

Oloye ofisa Lagos State Emergency Management Agency (LASEMA), Femi Oke-Osanyintolu, ni o fi idi eri iyape eeyan to ku mule, o ni awon ti n towo bo opa ep naa ni won ba opa epo NNPC je, ti won si n yo Premimum Motor Spirit(PMS) sinu tanka lita 33,000 nigba ti awon olopaa mu won.

O ni bi won se n gbiyanju lati sa mo awon olopaa ni die ninu epo naa danu ti won si dana si epo naa lati fi deruba awon olopaa, amo ina ti won da yii wa jo lo si ibi ti won baje lara opa epo naa ti ina naa fi di nla.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Arábìnrin ti da omi gbóná lu ọmọ.

Owo olopaati tearabinrin kan ti o da omi gbona lu oju ara omobinrin kekere kan ti n gbe ni…