Arákùnrin ọmọ Nàìjíríà kan ti kú sí ọgbà ẹ̀wọ̀n ní India.
Arakunrin omo odun merindinlogbon, Kumbha Roderick, ti se ewon lowo ni
orile-ede India ti ku si ewon.
Gege bi Times of India se so, Kumbha ku si ile iwosan district nibi ti o ti n gba itoju lowo ni ojo Wednesday, July 3.
Gege bi awon olopaa se so, won mu Kumbha ni September 30 odun 2018 fun esun pe, o duro koya akoko ti won fun ni ilu won, o se madaru nnkan ini idaabobo, o si se madaru lati le se iyanje.
Superintendent Mathura jail, Shailendra Maitrey, ti o fi idi eri isele naa mule, ni won gbe Kumbha lo si ile iwosan ni ojo Tuesday July 2 leyin ti o kero ailera. O si ailera re lekan si leyin ti o bere si ni bi ti won si gbe lo si ile iwosan district fun itoju nibi ti o dake si.
Maitrey ti ni won ma se ayewo lori iku re lati mo nnkan ti o fa a.
Arábìnrin ti da omi gbóná lu ọmọ.
Owo olopaati tearabinrin kan ti o da omi gbona lu oju ara omobinrin kekere kan ti n gbe ni…