Home ÀRÒJINLẸ̀ Arábìnrin ti fi ìyà jẹ́ ọmọ ọ̀dọ̀ rẹ̀ nítorí ó ké pe ìrànlọ́wọ́.

Arábìnrin ti fi ìyà jẹ́ ọmọ ọ̀dọ̀ rẹ̀ nítorí ó ké pe ìrànlọ́wọ́.

Laaarin awuyewuye ti n lo lowo nipa ifipabalopo, orisirisi obinrin lo ti n so awon nnkan ti oju won ti ri seyin nipa ifipabalopo. Bee ni a si ri awon obinrin miiran ti won ko ni aanu obinrin bi egebe won.

Arabinrin kan, Agatha Ayerite, ti so lori Facebook bi anti omo obinrin kan se fi iya je omo naa nitori egbon okunrin anti naa gbiyanju lati fi ipa ba omo naa lopo ti omo naa si ke sita fun iranlowo.

Agatha ni: “ejowo olori mo fe ki gbogbo aye ri aworan yii, eyi ninnnkan ti anti se fun omo ti n gbe ni odo re. Egbon okunrin anti naa ti o ba won lalejo gbiyanju lati fi ipa ba omo naa lopo, nitori omo naa ke sita fun iranlowo ni anti naa se lu omo naa bi i ilu bara.”

Iroyin ni, Lagos Island ni isele naa ti waye, ile iwe Lifiaji High School si ni omo naa n lo.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Arábìnrin ti da omi gbóná lu ọmọ.

Owo olopaati tearabinrin kan ti o da omi gbona lu oju ara omobinrin kekere kan ti n gbe ni…