Home iroyin Akẹ́kọ̀ọ́ àti olùkọ́ mefa ní Yunifásítì Madonna ti gba òmìnira.
iroyin - orisiirisii - Orisirisi - July 4, 2019

Akẹ́kọ̀ọ́ àti olùkọ́ mefa ní Yunifásítì Madonna ti gba òmìnira.

Awon akekoo ati oluko ile iwe giga Madonna ti wa ni ahamo lati February odun yii nitori nnkqn ti won ko nioa ile iwe naa si ori Facebook ti ile iwe naa si ni o pa awon lara, ti gba ominira won.

Ile ejo Federal High Court ni Awka ti Justice Babatunde Quadri bori e ti fun won ni beeli ni ana ojo Wednesday, leyin osu die seyin ti oludaabo koko gbe won lo si Okija campus ti yunifasiyi naa ti won fi won si ewon, ki won to wa gbe won lo si Awka prison.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Arábìnrin ti da omi gbóná lu ọmọ.

Owo olopaati tearabinrin kan ti o da omi gbona lu oju ara omobinrin kekere kan ti n gbe ni…