Home ÀRÒJINLẸ̀ Wọ́n ti da akẹ́kọ̀ọ́ àti olùkó Yunifásítì Madonna padà sí ẹ̀wọ̀n.

Wọ́n ti da akẹ́kọ̀ọ́ àti olùkó Yunifásítì Madonna padà sí ẹ̀wọ̀n.

Akekoo ati oluko Yunifasiti Madonna mefa ti won ti n fi oju ba ile ejo nitori nnkan ti won ko nipa ile iwe naa ti ile iwe naa ni o pa awon lara si ori Facebook ti pada si ewon leyin fi adajo ti o ye ki o da ejo, Babatunde Quadri o wa ni ana, July 2.

Ile ejo ti won won ni baali ni February, amo won si wa ni ewon nitori won o si san gbogbo nnkan ti baali naa bere fun.

Baba okan lara awon akekoo ti oro naa kan, Mr Christopher Onyejekwe, ni oun ti lo be oludasile ile iwe naa, Rev. Fr. Emmanuel Edeh, ni igba mokanla pe ki o dariji awon omo naa leyin ti ile ejo sun ejo naa si oni ojo Wednesday, amo Rev. Edeh fariga.

Punch ni Onyejekwe ni eketa ti won ma sun ejo naa re e leyin ti won ti fun won ni baali ti ile ejo naa o si jokoo fun ejo naa. O si ti leri pe oun ma ri pe awon obi akekoo igba o kere ju ma mu omo won kuro ni ile iwe naa.

Vice-Chancellor ile iwe naa Prof. Chuks Ezedum ti o fi esi si irokeke pe won ma mu awon omo won kuro ni ile iwe naa kii se ooto, pe awon ebi awon ti oro naa kan ni won n so eyi.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Arábìnrin ti da omi gbóná lu ọmọ.

Owo olopaati tearabinrin kan ti o da omi gbona lu oju ara omobinrin kekere kan ti n gbe ni…