Home iroyin Mo pá nítorí mo fẹ́ fi nnkan ọmọbìnrin ṣe owó – Bidemi.
iroyin - orisiirisii - Orisirisi - July 3, 2019

Mo pá nítorí mo fẹ́ fi nnkan ọmọbìnrin ṣe owó – Bidemi.

Awon olopaa ipinle Eko ti gbe arakunrin ti n je Bidemi leyin ti o pa arabinrin oni pansaga kan ti o gbe lo si ile re ni Corporation Estate ni Mile 2 lati ba ni ajosepo.

Iroyin ni, Bidemi ti n da gbe, gbe arabinrin kan wa si ile ni ago mokanla ale, awon ara ile si ri awon mejeeji bi won se wole, ko pe ni won gbo igbe arabinrin naa.

Awon ara ile si pe akiyesi awon ti n so agbegbe naa si nnkan ti n sele, ko pe ni Bidemi bota ti o si fe jade kuro niunu estate, nigba naa ni awon ti n so ile da duro ti won si bere arabinrin ti won jo wole lowo re, o si paro pe o wa ni ile, won si ni awon gbo igbe re pe awon fe ri.

Bidemi si n gbiyanju lati salaye pe ko si wahala, amo won ko gbo tie, won si fi ipa mu lo si ile, bi won se de ile, won ba arabinrin naa ninu agabara eje ti o ti ge nnkan omobinrin re, nigba ti won bi i, o ni oun fe fi nnkan omobinrin re se owo ni.

Won si faa le awon olopaa Amuwo Odofin lowo.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Arábìnrin ti da omi gbóná lu ọmọ.

Owo olopaati tearabinrin kan ti o da omi gbona lu oju ara omobinrin kekere kan ti n gbe ni…