Home iroyin Kàyéfì : Òṣìṣẹ́ kọ̀m̀pútà tí ó ṣèṣẹ̀ gba fisa Canada ti pa ara rẹ̀.
iroyin - orisiirisii - Orisirisi - July 3, 2019

Kàyéfì : Òṣìṣẹ́ kọ̀m̀pútà tí ó ṣèṣẹ̀ gba fisa Canada ti pa ara rẹ̀.

Arakunrin kan Muyiwa Olushola, ti n sise komputa ti ko ebinrw sinu inpbanuje leyin ti o fi oogun p’efon (sniper) sinu oti re, ti o si pa ara re ni agbegbe Masadolorun ni Iba Local Council Development Area ni ipinle Eko.

Awon ara ile won ni iya oloogbe naa lo fun isoji, ti o si fi baba re, Segun ati aburi re obinrin, Tosin, nigba ti o bere sinu pariwo ni oru, won si gbayanju lati ja wo yara re. Nigba won wo yara re, won ba Muyiwa ni ile nibi ti o ti n tu ose jade lenu.

Gege bi Punch se so, won si sare gbe lo si ile iwosan, ona ni o ti dake. Iwadii fi han pe oogun p’efon (sniper) ni o mu nitori won ri ike oti ati ike sniper meji ati koopu ninu yara re.

Lowolowo bayii, won ti ti ile ti oloogbe ati ebi re n gbe. Okan lara ara ile won ni ariwo Muyiwa ati bi won se n kọn ileku lo ji awon ni oru.

Ara adugno kan ti n je Kamoru ni ironu lo fa iku Muyiwa, o si ni isele naa ti je ki awon ebi re ko kuro nibi ti won n gbe tele lo si ibomiran.

Ore re kan, Babjide Adekunle ni Muyiwa sese gba fisa orile-ede Canada, pe o ye ki o rin irinajo naa ni October.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Arábìnrin ti da omi gbóná lu ọmọ.

Owo olopaati tearabinrin kan ti o da omi gbona lu oju ara omobinrin kekere kan ti n gbe ni…