Home iroyin Ilé ìwé gíga Unizik ti lé ọkàn lára àwọn olùkọ́ wọn.
iroyin - orisiirisii - Orisirisi - Social Good - July 3, 2019

Ilé ìwé gíga Unizik ti lé ọkàn lára àwọn olùkọ́ wọn.


Awon igbimo ile iwe giga ti Unizik tinle okan lara awon okuko won ni eka Pure and Industrial Chemistry ni Faculty of Physical Scienece, Nnamdi Azikiwe University, Dr Peter Ekemezie.

Won fi esun kan Ekemezie pe o se madaru iwe eri Bsc re lati yunifasiti Port Harcourt, Rivers. Ile iwe naa si da igbimo sile lati se iwadii oro naa, aseyinwa aseyinbo, won ri pe o se madaru iwe eri naa.

Akowe igbimo naa, Philomena Okoye, so ninu leta pe pelu ilana oin ile iwe naa, won ma fun Ekemezie ni iwe gbéléẹ.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Arábìnrin ti da omi gbóná lu ọmọ.

Owo olopaati tearabinrin kan ti o da omi gbona lu oju ara omobinrin kekere kan ti n gbe ni…