Home iroyin Àwọn olè ti pa àwọn ọlọ́pàá méjì tí ń tẹ̀lé ọkọ̀ owó ní Ìpínlẹ̀ Port Harcourt.

Àwọn olè ti pa àwọn ọlọ́pàá méjì tí ń tẹ̀lé ọkọ̀ owó ní Ìpínlẹ̀ Port Harcourt.

Awon ole ti yin ibon pa awon olopaa meji ti won so mo ile ise ti n pin oti beer ti o wa ni Nwachukwu/Ojoto street ni Port Harcourt, Rivers ni aaro ojo Monday.

Awon ole naa ko owo lo, won si yin ibon pa awon olopaa ti n tele okoti n gbe owo lo si ile ifowopamo. Isle naa waye ni ago mesan aaro ni Ojoto-Timber, Mile Two, Diobu, ti o sunmo ago olopaa. Awon ole naa pa awon olopaa naa, won si ko ibon won lo.

Eni ti isle naa se nisoju re ni, awon ole naa ti n tele oko ile ise beer naa, won si ko si won niwaju, won si bere sini yin ibon pelu awon olopaa naa. Diraba oko naa sese ni ese re, awon eeyan ti n koja lo naa si farapa.

Leyin igba ti awon odaran naa ti salo, awon kan de won si gbe oku awon ara won ti o wa ninu oko Toyota Camry.

Agbenuso awon olopaa ipinle naa, DSP Nnamdi Omoni, lo fi idi eri isele naa mule, o si ni komisona olopaa Usman Bele ti ni ki won se iwadii nipa isele naa.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Arábìnrin ti da omi gbóná lu ọmọ.

Owo olopaati tearabinrin kan ti o da omi gbona lu oju ara omobinrin kekere kan ti n gbe ni…