Home ÀRÒJINLẸ̀ Àwọn ọ̀dọ́ ti dáná sun àgó ọlọ́pàá ní ìpínlè Imo.

Àwọn ọ̀dọ́ ti dáná sun àgó ọlọ́pàá ní ìpínlè Imo.

Awon odo irate ti dana sun ago olopaa ni Obowo Local Government Area ni ipinle Imo ni ojo Monday, nitori olopaa kan, yin ibon pa okunrin kan ti n je Ikenna Ukachi.

Leyin ti olopaa naa pa okunrin naa tan, o ju ibon re sile o si salo ki owo to te e.

Ipa ti o pa arákùnrin omo odun marundinlogbon naa lo fa wahala si agbegbe naa.

Àwọn odo si ko ra won jo lo si ago olopaa naa lati fi edun okan won han. Eyi lo fa a ti awon eeyan kan si darapo mo won ti won si fi ibinu dana sun ago olopaa naa.

Iroyin ni, EDS Plaza ni Umuokeh, Obowo ni won ti yin ibon pa arakunrin naa.

Awon odo si fi ibinu di ona ti n lo si ago olopaa naa, bi awon olopaa na se ri won lati ookan ni won mu ere sa fun emi won.

Awon odo yii si fi ibinu ya wo ago olopaa naa ti won ko gbogbo nnkan won ti won si dana sun ago olopaa naa.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Arábìnrin ti da omi gbóná lu ọmọ.

Owo olopaati tearabinrin kan ti o da omi gbona lu oju ara omobinrin kekere kan ti n gbe ni…