Home iroyin Arábìnrin kan ti gbìyànjú láti pa ara rẹ̀ ní Ìpínlẹ̀ Kogi.
iroyin - orisiirisii - Orisirisi - July 3, 2019

Arábìnrin kan ti gbìyànjú láti pa ara rẹ̀ ní Ìpínlẹ̀ Kogi.

Won ti gba arabinrin ti o be si odo lati gba emi ara re ni ojo Monday ni ipinle Kogi.

Iroyin ni, arabinrin bole ninu keke maruwa, o fi eru re sile, o si be si odo.

Adupe pe eeyan kan tete be tele sinu omi naa, ti o si gba a sile.

Kí Ọlọ́run ṣàánú fun orile-ede Naijiria pelu orisirisi iroyin ti a n gbo nipa bi awon eeyan se n gbiyanju lati gba emi ara won.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Arábìnrin ti da omi gbóná lu ọmọ.

Owo olopaati tearabinrin kan ti o da omi gbona lu oju ara omobinrin kekere kan ti n gbe ni…