Home ÀKỌ̀TUN Wàhálà n rúgbó bo̩ lórí RUGA – Soyinka
ÀKỌ̀TUN - orisiirisii - Orisirisi - July 2, 2019

Wàhálà n rúgbó bo̩ lórí RUGA – Soyinka

Ojogbon Wole Soyinka ti o mo iwe dunju ni “aiba won si nibe ni aiba won da sii”. Eyi lo mu ki o sin ijoba apapo ni “gbere ipako” pe, oro awon Fulani darandaran nilo amojuto gidi.
O ni kii se oro ti a maa gba bi eni gba igba oti nitori aburu ti oro naa ti da sile ti po ju.
Soyinka ni “ko si ibi ti won ko ki ti n dana ale, omi obe nikan lo dun ju ara won lo”.
O ni gbogbo awon ilu ti won ti dagba lonii pata naa lo n je eran maluu. O ni kin lo de ti ko fa ijongbon fun awon eniyan won?.
Ojogbon yii tun ni eran maluu ko ki n se ajoji si wa ni orileede yii, o ni bawo ni a se n sin awon maluu naa ki oselu to ba gbogbo re je?
Soyinka ro ijoba lati ma se fi owo yepere mu oro awon Fulani naa nitori pe ara n kan awon eniyan ti won ti pa awon ebi won, awon ti won ti ba oko won je ati bee bee lo.
Soyinka ni oro awon maluu ko gbodo mumu laya ijoba apapo ju omo eniyan lo.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Nítorí ẹ̀sùn ìfipábánilòpọ̀, àwọn aláṣẹ Fásitì KWASU lé olùkọ́ kan dànù

Nítorí ẹ̀sùn ìfipábánilòpọ̀, àwọn aláṣẹ Fásitì KWASU lé olùkọ́ kan dànù Ọrẹ Òtítọ́jù Àwọn …