Irinwó ẹlẹ́rìí ń bẹ fún mi – Atiku
Oludije du ipo Aare labe egbe oselu PDP, Alhaji Atiku Abubakar ni agbejoro re Dr. Livy Uzoukwu (SAN) n gbenu re soro ni aipe yii.
O ni gbogbo eri to daju ni o wa ni ikawo oun ati egbe oselu PDP, o ni egbe oselu APC ko wole ibo ojo ketalelogun osu keji ti awon di ibo Aare ni orileede yii.
O ni ki ile-ejo dakun dabo gba oun ati egbe PDP laaye lati je ki gbogbo aye ri eri ti awon ko dani.
Àwọn òṣìṣẹ́, Shoprite, bẹ̀rẹ̀ ìfẹ̀hónúhàn káàkiri àwọn ìpínlẹ̀ kan ní Nàìjíríà.
Àwọn òṣìṣẹ́, Shoprite, bẹ̀rẹ̀ ìfẹ̀hónúhàn káàkiri àwọn ìpínlẹ̀ kan ní Nàìjíríà. Orẹ Òtítọ́…