Home ÀKỌ̀TUN DPO tí wó̩n pa ba IGP ló̩kàn jé̩
ÀKỌ̀TUN - orisiirisii - Orisirisi - July 1, 2019

DPO tí wó̩n pa ba IGP ló̩kàn jé̩

Jinni-jinni da bo awon ara ilu Agudama ni ipinle Bayelsa ni osan oni, nigba ti awon agbebonrin kan ya wo ago olopaa naa ti won si da ibon bole.
Won pa oga olopaa, alaboyun kan pelu awon olopaa meji miran.
Eyi ba gbogbo awon ara ilu leru pe eemo lo wo ilu naa, nitori pe awon olopaa ti won maa n lo sa ba naa ni awon kan ti fi ibon tu gbogbo ile won ka yii.
Bi iroyin buruku naa se ta si oga olopaa patapata Mohammadu Adamu ni o ti da awon otelemuye si ita pe, won gbodo fi owo sinkun ofin mu awon odaran naa.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Àwọn wọ̀nyí ti kékeré dèrò ẹ̀wọ̀n, jìbìtì orí ayélujára ló kó bá wọn

Àwọn wọ̀nyí ti kékeré dèrò ẹ̀wọ̀n, jìbìtì orí ayélujára ló kó bá wọn Ọrẹ Òtítọ́jù Àwọn ló …