Home Entertainment Wọ́n ń wá ọmọbìnrin ọlọ́dún kẹrin ní RSUST lẹ́yìn tí ó kọ ìwé sílè pé òun ma pa ara òun, kí wón sì gbé òkú òun jẹ fún olùkó kan.
Wọ́n ń wá ọmọbìnrin ọlọ́dún kẹrin ní RSUST lẹ́yìn tí ó kọ ìwé sílè pé òun ma pa ara òun, kí wón sì gbé òkú òun jẹ fún olùkó kan.
Won n wa omobinrin olodun kerin ni ile iwe giga Rivers State University of Science and Technology, Kpagane Desire, leyin ti o koniwe sile pe oun ma pa ara oun.
Ki won to bere si ni wa Desire, ninojo Wednesday June 26, o ko si ori Facebook pe oun ma pa ara oun ki won si gbe eran ara oun je fun oluko kan ti n je Dr. Paul Nadure ni ile iwe naa.
Arábìnrin ti da omi gbóná lu ọmọ.
Owo olopaati tearabinrin kan ti o da omi gbona lu oju ara omobinrin kekere kan ti n gbe ni…