Home Entertainment Pásítọ̀ Tony Rapu ti ṣàlàyé ìdí tí àwọn olórí o ṣe ní ìgboyà láti ṣe nǹkan to tọ lórí ọ̀rọ̀ ìfipábálòpọ̀.

Pásítọ̀ Tony Rapu ti ṣàlàyé ìdí tí àwọn olórí o ṣe ní ìgboyà láti ṣe nǹkan to tọ lórí ọ̀rọ̀ ìfipábálòpọ̀.

Laaarin gbogbo rògbòdìyàn ti n lo lori afefe nipa esun ti won fi kan pasito Biodun Fatoyinbo, eniyan olorun miiran, Pasito Tony Rapu ti so ana ti awon eeyan le gba lati mu iru isele bayii.

Gege bi Tony Rapu se so “opolopo awon olori ni won ko ni igboya lati yanyu oro ifipabalopo nitori won ko ni imo to peye lati ti mu awon idiwon ti o ma n wa ninu isele naa”.

“Arabinrin on miiran o ni tireni to peye lati fi mu awon italaya ti iru isele ifipabalopo tabi ki won maa na obinrin ma n wu jade. A nilo imo bi won se n yanju isele ifipabalopo pelu ilana olorun”.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Arábìnrin ti da omi gbóná lu ọmọ.

Owo olopaati tearabinrin kan ti o da omi gbona lu oju ara omobinrin kekere kan ti n gbe ni…