Home orisiirisii Ọ̀pọ̀lọpọ̀ ọkọ̀ lo tí jóná lẹ́yìn tí ọgbà mẹkáníkì gbiná.
orisiirisii - Orisirisi - ỌRỌ̀-AJÉ - June 29, 2019

Ọ̀pọ̀lọpọ̀ ọkọ̀ lo tí jóná lẹ́yìn tí ọgbà mẹkáníkì gbiná.

Awon makaniiki kan n banuje lowo leyin ti ogba mekaniiki kan ni oregun, ipinle Eko ti gbina. Opolopo oko ni won si padanu.

Ina naa bere ni owo aaro mo osan eni June 29.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Arábìnrin ti da omi gbóná lu ọmọ.

Owo olopaati tearabinrin kan ti o da omi gbona lu oju ara omobinrin kekere kan ti n gbe ni…