Home Èfè ati Àwàdà Onílé kan ní Ki àwọn obìnrin tí wón bá wọ ṣòkòtò gígùn àti ṣòkòtò péńpé ma wọ ilé òun.

Onílé kan ní Ki àwọn obìnrin tí wón bá wọ ṣòkòtò gígùn àti ṣòkòtò péńpé ma wọ ilé òun.

Arakunrin kan ti gbe aworan ile ti n gbe tele si ori instagram,ki landlord tuntun tino je ara ijo Deeper life to fun gbogbo awon ni iwe pe ki won ko jade.

O ni oun bo lati ibikan oun wa gba iwaju ile naa koja, onilennaa wa gbe patoko kannsi iwaju ie naa ti o ko si ori re ni pe ki awon obinrin ti won ba n wo sokoto gigun ati sokoto penpe ma wo ile oun.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Arábìnrin ti da omi gbóná lu ọmọ.

Owo olopaati tearabinrin kan ti o da omi gbona lu oju ara omobinrin kekere kan ti n gbe ni…