Home orisiirisii Arábìnrin ọmọ ogún ọdún ti gún ọkọ rẹ pa ní Ìpínlẹ̀ Anambra.
orisiirisii - Orisirisi - June 29, 2019

Arábìnrin ọmọ ogún ọdún ti gún ọkọ rẹ pa ní Ìpínlẹ̀ Anambra.

Awon olopaa ipinle Anambra ti gbe omo ogun odun Makoduchukwu Ndubisi, fun esun pe o gun oko re omo odun marundinlogoji John Bosco Ngu pa.

Ninu gbolohun ti won fi kale, arabinrin naa gunnoko re ni sya pelu obe to mu ninile ni No 16 Donking Street, Nsugbe ni Anambra East LGA ni ipinle Anambra.

Win gbe okunrin naa lo si ile iwosan Boromeo ni Onitsha fun itoju, amo dokita ni o ti ku bi won se gbe de ibe. Won ti gbe oku re lo si mosuari fun ayewo.

Arabinrin naa wa ni ago olopaa, won si ma to gbe lo si ile ejo.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Arábìnrin ti da omi gbóná lu ọmọ.

Owo olopaati tearabinrin kan ti o da omi gbona lu oju ara omobinrin kekere kan ti n gbe ni…