Home ERÉ ÌDÁRAYÁ AFCON 2019: Mali ti dá Agbábọ́ọ́lù wọn, Adama Niane padà sí ilé lẹ́yìn tí ó fọ olórí wọn létí.
AFCON 2019: Mali ti dá Agbábọ́ọ́lù wọn, Adama Niane padà sí ilé lẹ́yìn tí ó fọ olórí wọn létí.
Malian Football Federation ti da Adama Niane padà sí ilé láti Africa Cup of Nations ti won n gba lowo ni Egypt leyin ti o gba olori egbevwon Abdoulay Diaby leti.
Gege bi Footmali se so, isele naa waye leyin ti awon agbaboolu fun Mali pe onidiri wa si ilé ìtura won, bi o se de ni Diaby sare jokoo si ori aga onidiri naa. Eyi ko si ba Niane lara mu, o si pakuru mo Diaby ki o to fo leti.
Oniroyin fun egbe na, Ibrahim Coulibaly ti fi idi eri mulu pe won ti le Niane lo si ile.
Arábìnrin ti da omi gbóná lu ọmọ.
Owo olopaati tearabinrin kan ti o da omi gbona lu oju ara omobinrin kekere kan ti n gbe ni…