Home orisiirisii Wọ́n ti mú àwọn olè méjì tí ń jí ọkọ̀ ní Ìpínlẹ̀ Anambra.
orisiirisii - Orisirisi - June 28, 2019

Wọ́n ti mú àwọn olè méjì tí ń jí ọkọ̀ ní Ìpínlẹ̀ Anambra.

Awon olopaa ipinle Anambra ti mu awon ole meji ti won ma n ji oko awon ti n gbe ni ipinle naa.

Ninu gbolohun ti agbenuso won so, Haruna Mohammed, o ni awon olopaa ago olopaa ti Onitsha ati awon olopaa ti n duro si opopona Enugu, ti mu Ifeanyi Jude, omo odun marundinlogbon, ni ipinle Enugu.

Gege bi awon olopaa se so, arakunrin ati enikeji re, Okwudiki Okoli, omo ogbon odun, jo ji omo Toyota Corollati nomba re je HRH-01-NEN ti o je ti Oba Robert Nwankwo ninu ile re ni No. 1 Nigrt Drive GRA, Onitsha ni ipinle Anambra.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Arábìnrin ti da omi gbóná lu ọmọ.

Owo olopaati tearabinrin kan ti o da omi gbona lu oju ara omobinrin kekere kan ti n gbe ni…