Home ÀRÒJINLẸ̀ Wàhálà ní ìpínlè Imo, Gómìnà Ihedioha ti rán àwọn ọlọ́pàá láti lọ kó aṣọ, àga , àti fírìgì ní ṣọ́ọ̀bù ọmọ Okorocha obìnrin.

Wàhálà ní ìpínlè Imo, Gómìnà Ihedioha ti rán àwọn ọlọ́pàá láti lọ kó aṣọ, àga , àti fírìgì ní ṣọ́ọ̀bù ọmọ Okorocha obìnrin.

Wahala be sile ni ale Thursday ni Owerri, ipinle Imo leyin ti awon odo ti won ba Igbimo ipinle Imo sise lo si ile oja kan (House of Freeda) ti o je ti omo gomina ana ipinle naa, nitori won n wa ogun ipinle.

Ogun ati oja bi i aga, aso ati firigi ni won ko lo, won si se awon osise bii mefa leae, ti o si je pe alaga igbimo naa, Hon Jasper Ndubuaku lo n se asaju won.

Gege bi eni ti isele naa soju re se so, o nimawon olopaa ati odo naa fi pa wonu ile oja ti o je pe orisirisi eeyan ti won ko tan mo gomina naa lo n ta oja nibe, won si bere si ni ko awon oja olowo nla ti won fi pate.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Arábìnrin ti da omi gbóná lu ọmọ.

Owo olopaati tearabinrin kan ti o da omi gbona lu oju ara omobinrin kekere kan ti n gbe ni…