Home ÀRÒJINLẸ̀ Pásítọ̀ COZA, Biodun Fatoyinbo ti fi èsì sí e ẹ̀sùn tí ìyàwó akọrin Timi Dakolo, Busola Dakolo fi kàn án pé ó fi ipá bá òun ní àjọṣepò.

Pásítọ̀ COZA, Biodun Fatoyinbo ti fi èsì sí e ẹ̀sùn tí ìyàwó akọrin Timi Dakolo, Busola Dakolo fi kàn án pé ó fi ipá bá òun ní àjọṣepò.

Pasito COZA, Biodun Fatoyinbo, ti ni oun o mo nnkankan nipa esun ti iyawo Timi Dakolo, Busola fi kan oun. Ninu gbolohun ti o fi kale ni irole yii, Fatoyinbo ni oun o fi ipa bi obinrin lopo ri. O si ni Timi ati iyawo re, Busola n wa ogbon lati gba owo lowo oun ni.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Arábìnrin ti da omi gbóná lu ọmọ.

Owo olopaati tearabinrin kan ti o da omi gbona lu oju ara omobinrin kekere kan ti n gbe ni…