Home orisiirisii Ọlọ́pàá ìpínlè Bauchi tí gbe arákùnrin oníṣòwò tí ó p’arọ́ pé wọ́n jí òun gbé.
orisiirisii - Orisirisi - June 28, 2019

Ọlọ́pàá ìpínlè Bauchi tí gbe arákùnrin oníṣòwò tí ó p’arọ́ pé wọ́n jí òun gbé.

Olopaa ipinle Bauchi ti gbe arakunrin onisowo kan ni ipinle Nassarawa, Abdullahi Mihammed, fun esun pe o para pe won ji oun gbe.

Agbenuso fun olopaa ipinle na, Abubakar Kamal ni, Tijani Mohammed kan ti Sabon Fegi ni Lafis, Nassarawa, ni ojo May 12, wa fi ejo sun egon oun Mohammed, kuro nile fun iranajo ise ni ipinle Kano, ko si de ni asiko to ye.

Mohammed pe Tijani pe won ti ji oun gbe, won si n beere fun milionu mewaa ki won to le fi oun sile. Mohammed tun pada pe wipe won ti din owo naa ku si milionu kan pe ki o gbe wa si Bauchi.

Agbenuso fun olopaa ni awon olopaa ti n wa awon ajinigbe na, ti gbe Haruna Saidu kan lati Gamawa local government ni Bauchi, ti o wa gbe owo na.

Kamal ni “ iwadii fi han pe Abdullahi Mohammed, onisowo, leyin ti owo re wo lule, o pada apupo peku Haruna Saidu lati paro pe won ji oun gbe ki o le ri owo gba lowo awon abi re”

Kamal ni won ma gbe won lo si ile ejo ti won ba pari iwadii.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Arábìnrin ti da omi gbóná lu ọmọ.

Owo olopaati tearabinrin kan ti o da omi gbona lu oju ara omobinrin kekere kan ti n gbe ni…