Home ÀRÒJINLẸ̀ Ìyàwó akọrin Timi Dakolo, Busola Dakolo ti ṣàlàyé pé Pásítọ̀ kan fi ipá bá òun lòpọ̀.
ÀRÒJINLẸ̀ - iroyin - orisiirisii - Orisirisi - June 28, 2019

Ìyàwó akọrin Timi Dakolo, Busola Dakolo ti ṣàlàyé pé Pásítọ̀ kan fi ipá bá òun lòpọ̀.

Iyawo akorin Timi Dakolo, Busola Dakolo ti salaye pe Pasito Biodun Fatoyinbo ti COZA fi ipa ba oun lo po ni opolopo igba nigba ti oun wa ni omo odun metadinlogun.

Busola ni, oun o ti mo okunrin nigba ti pasito naa fi ipa ba oun lopo ni omo odun matadinlogun. O ni leyin ti Pasito naa fi ipa ba oun lo po ninu palo mama oun, Pasito Biodun naa so fun oun pe o ye ki inu oun maa dun nitori eniyan olorun lo gba ibale oun.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Arábìnrin ti da omi gbóná lu ọmọ.

Owo olopaati tearabinrin kan ti o da omi gbona lu oju ara omobinrin kekere kan ti n gbe ni…