Home iroyin Iná òjò ti pa ọmọdé mẹ́ta ní orílẹ̀ èdè Uganda.
iroyin - orisiirisii - Orisirisi - June 28, 2019

Iná òjò ti pa ọmọdé mẹ́ta ní orílẹ̀ èdè Uganda.

Ina ojo ti pa omode meta ni ojo Wednesday ni agbegbe Kibaale, ni iwo oorun Uganda.

Olopaa ati awon ti n gbe ni agbegbe naa ti da awon omo naa mo bi i, Robert Zabayo, omomodun merinlelogun ni ile iwe alakoobere Kisalizi, aburo re Mababazi Marina, omo dun mefa ati ore re Moses Alinaitwe, omo odun mewaa.

Zabayo ati Mbabazi je omo Obed Byomugisa, Alinaitwe je omo Ayebale, won jo n gbe ni ilu Kyenkonge ni agbegbe Kyebando Sub County.

Ina pa awon metata ni ile Byomugisa nigba ti won n sa fun ojo ni irole ojo Wednesday.

Awon omo naa sese de lati ile iwe, won si n sere ni ita nigba ti ojo naa bere. Won si sa fun ojo ni ile Byomugisa.

Awon olopaa lo si ibi ti isele naa ti se, won si beere oro lowo awon ti isele naa se oju won.

Olopaa agbegbe Kibaale, Ogbeni David Otabong ti gba awon ni imoran pe ki won so nnkan ti o ma ta ina pada si ori ile onikaluku.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Arábìnrin ti da omi gbóná lu ọmọ.

Owo olopaati tearabinrin kan ti o da omi gbona lu oju ara omobinrin kekere kan ti n gbe ni…