Home orisiirisii Arábìnrin da ata sí ojú ọmọ ọ̀rẹ́kùnrin ọmọkùnrin ọdún mẹ́sàn-àn.
orisiirisii - Orisirisi - June 28, 2019

Arábìnrin da ata sí ojú ọmọ ọ̀rẹ́kùnrin ọmọkùnrin ọdún mẹ́sàn-àn.

Arabinrin omo odun metadinlogbon, Nelly Antai, ti so omo orekunrin re omo odun mesan-an pelu okun, o si da ata sii loju.

Won ti fi esun ipalara ibaje sun Antai ti n gbe pelu orekunrin re ni No 11, Mogaji Street, Ijeshatedo, Surulere, Eko.

Agbejero fun eni ti won fi esun kan, Sgt. Anthonia Osayande so pe Antai wu iwa na no June 15 ni ile naa.

Osanyande ni Antai, ti o sese ko wole pelu orekunrin re ti ma n soro nipa bi omo naa se ma n pe wole.

O ni omo naa tun pe wole, Antai si so o mole, o si da ata tutu si gbogbo ara re.

Adajo, Mrs Oluyemisi Adeleja ti ni ki o san baali egberun lona ogorun naira, pelu awon eeyan ti won ma duro fun.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Arábìnrin ti da omi gbóná lu ọmọ.

Owo olopaati tearabinrin kan ti o da omi gbona lu oju ara omobinrin kekere kan ti n gbe ni…