Adájọ́ tó ní kí wọn lọ gbé Diezani ti di olóògbé.
Adajo ti Federal Capital Territory (FCT), Adajo Valentine Ashi, ti o ni ki won lo gbe minisita fun epo ana, Diezani Alison-Madueke laaarin wakati 72 ti ku.
A gbo pe adajo naa ku ni ojo Thursday June 27 ni ile iwosan kan ni Abuja, leyin ti o se aisan ti won ko so sita.
Arábìnrin ti da omi gbóná lu ọmọ.
Owo olopaati tearabinrin kan ti o da omi gbona lu oju ara omobinrin kekere kan ti n gbe ni…