Home iroyin Ọlọ́pàá ti gbé aṣòfin tí ó ní òun má a na àwọn oníṣòwò àjèjì tí wọn kò bá kúrò ní ìlú.

Ọlọ́pàá ti gbé aṣòfin tí ó ní òun má a na àwọn oníṣòwò àjèjì tí wọn kò bá kúrò ní ìlú.

Won ti gbe Charles Njagua Kanyi, osofin ni orile-ede Kenya leyin ti o ni oun maa na awon onisowo ajeji ti won ko ba kuro ni ilu awon ni kiakia.

Charles so ninu fidio pe awon omo Tanzania and Uganda ti n gori owo sise ni Kenyan “o si ti to ge”. Fidio naa bo si ori afefe, prime minisita Tanzania si pe arakunrin naa pe ki o wa salaye ara re.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Arábìnrin ti da omi gbóná lu ọmọ.

Owo olopaati tearabinrin kan ti o da omi gbona lu oju ara omobinrin kekere kan ti n gbe ni…