Home iroyin JAMB ti fa èsì ìdánwò àwọn akẹ́kọ̀ọ́ mẹ́rin padà.
iroyin - orisiirisii - Orisirisi - June 27, 2019

JAMB ti fa èsì ìdánwò àwọn akẹ́kọ̀ọ́ mẹ́rin padà.

The Joint Admissions and Matriculation Board(JAMB) ti fa esi idanwo awon akekoo merin pada.

Ninu gbolohun ti olori alaye(information), Dr. Fabian Benjamin, fi kale ni ana June 26, o ni awon akekkoo naa ni Adah Eche ti nomba re je 97512230IB, Taiwo Abisola Omowunmi ti nomba re je 97049254GG, Vincent Oyinyechi Prisca ti nomba re je 96531098BC ati Sofodun Afolasade Zainab ti nomba re je 96634599GA.

Gege bi Benjamin se so, awon akekoo meta n gbiyanju ati se madaru esi idanwo naa.

Won mu Eche ni ojo Monday, nitori o gbiyanju lati su esi idanwo soke lati 153 si 290, pelu iranlowo eni ti n se jibiti idanwo.

Yato si pe won ba esi idanwo faaki lowo re, o n gbiyanju atinran awon ti oruko won wa loke lati sun esi idanwo ti won naa soke.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Arábìnrin ti da omi gbóná lu ọmọ.

Owo olopaati tearabinrin kan ti o da omi gbona lu oju ara omobinrin kekere kan ti n gbe ni…