Home iroyin Ilé ìjọsìn Celestial ń béèrè fún ìrànlọ́wọ́ fún àwọn ọmọdé mẹ́ta tí bàbá wọn àti ìyàwó rè ń fi ìyà jẹ nítorí ìyá wọn ti kú.
iroyin - orisiirisii - Orisirisi - June 27, 2019

Ilé ìjọsìn Celestial ń béèrè fún ìrànlọ́wọ́ fún àwọn ọmọdé mẹ́ta tí bàbá wọn àti ìyàwó rè ń fi ìyà jẹ nítorí ìyá wọn ti kú.

Ile ijosin Celestial Church of Christ ti Onipepeye n beere fun iranlowo fun awon omode meta ti baba won ati iyawo baba won n fi iya je ni agbegbe Mpape ni Abuja.

Gege bi eni ti o gbe isele naa si ori Facebook se so, o ni, iya awon omo naa, Bose Adedeji ti salaisi, o si fi awon omo naa sile pelu baba wo ti o je osise National Productivity Center Abuja.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Arábìnrin ti da omi gbóná lu ọmọ.

Owo olopaati tearabinrin kan ti o da omi gbona lu oju ara omobinrin kekere kan ti n gbe ni…