Home iroyin Igbákejì Ààrẹ Yemi Osinbajo lo kí Igbákejì Ààrẹ orílẹ̀ èdè America, Mike Pence.

Igbákejì Ààrẹ Yemi Osinbajo lo kí Igbákejì Ààrẹ orílẹ̀ èdè America, Mike Pence.

Igbakeji aare Yemi Osinbajo lo ki igbakeji aare orile-ede America, Mike Pence ni ile ijoba(white house).

Erongba ipade won lati je ki ibasepo orile-ede Naijiria ati America tubọ rinle si.

Leyin ipade naa, igbakeji aare orile-ede America Pence sin olejo omo Naijiria re si idi oko re, o si pe Osinbajo ni ore re.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Arábìnrin ti da omi gbóná lu ọmọ.

Owo olopaati tearabinrin kan ti o da omi gbona lu oju ara omobinrin kekere kan ti n gbe ni…