Ibi ti ré kọjá lẹ́yìn tí bírèkì ọkọ̀ tírálà fáìlì ní Ikorodu.
Ibi ti re koja leyin ti bireki oro tirala faili ni Ikorodu. Isele naa waye ni Garage bus stop nibi ti awon onisowo pate ojo si lorisirisi ni oju titi. Adupe pe emi kankan o lo si.
Arábìnrin ti da omi gbóná lu ọmọ.
Owo olopaati tearabinrin kan ti o da omi gbona lu oju ara omobinrin kekere kan ti n gbe ni…