Home iroyin Gómìnà Okowa ti fún mọ̀lẹ́bí ọmọbìnrin ọlọ́dún kẹta ní DELSU tí àwọn tí ń fi èèyàn ṣe owo pa ní mílíọ̀nù naira mefa.
iroyin - orisiirisii - Orisirisi - June 27, 2019

Gómìnà Okowa ti fún mọ̀lẹ́bí ọmọbìnrin ọlọ́dún kẹta ní DELSU tí àwọn tí ń fi èèyàn ṣe owo pa ní mílíọ̀nù naira mefa.

Gomiba ipinle Delta, Srnator Dr. Ifeayin Okowa ti won molebi omo olodun keta ni eka (mass communications) ni ile iwe Yunifasiti ipinle Delta, Abraka, Elozino Ogege ni milionu naira meta fun iranlowo.

Awon agbenipa pa Elozino ni November 15, 2018, leyin ojo merin ti won ti n wa.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Arábìnrin ti da omi gbóná lu ọmọ.

Owo olopaati tearabinrin kan ti o da omi gbona lu oju ara omobinrin kekere kan ti n gbe ni…