Home orisiirisii Èyí ga: Ìyá àti ọmọ lo fi ẹjọ́ sun ọlọ́pàá nítorí ẹni tí wón san owó fún láti pa èèyàn o ṣe iṣẹ́ tí wọ́n ran.
orisiirisii - Orisirisi - Social Good - June 27, 2019

Èyí ga: Ìyá àti ọmọ lo fi ẹjọ́ sun ọlọ́pàá nítorí ẹni tí wón san owó fún láti pa èèyàn o ṣe iṣẹ́ tí wọ́n ran.

Iya, omo aadota odun, ati omo re obinrin, omo ogun odu, lo fi ejo sun olopaa nitori eni ti won san owo fun lati pa eeyan o je ise naa.

Iya ati omo san egberun pound naira fun orekunrin omo naa lati pa orekunrin iya naa ki won si ta ifun re nitori o so fun won pe osise ijoba ni oun, oun si nilo owo lati paa.

Iya ati omo lero pe ti won ba ta ifun naa, awon,maa ri 60,000 pound ti won ji lowo iya naa.

Amo orekunrin omo naa o si je ise naa, won si lo fi ejomre sun olopaa.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Arábìnrin ti da omi gbóná lu ọmọ.

Owo olopaati tearabinrin kan ti o da omi gbona lu oju ara omobinrin kekere kan ti n gbe ni…