“Ẹkú orí irẹ ẹ̀yin Àgùnbánirọ̀ tí ẹ ṣẹ̀ṣẹ̀ ṣe tán” – oníṣẹ́ orin, Samklef.
Onise orin, Samklef n ki awon agunbaniro ti won sese setan pe ki won ku ori ore ki won n si wa ise kun ise owo wọn, pe ki won ma gbe okan le ijoba nítorí won o ni eto fun won.
Arábìnrin ti da omi gbóná lu ọmọ.
Owo olopaati tearabinrin kan ti o da omi gbona lu oju ara omobinrin kekere kan ti n gbe ni…