Home iroyin Èèyàn méjìlá ti ṣèṣe lẹ́yìn tí ilé olókè mẹ́ta wó ní Èkó.
iroyin - orisiirisii - Orisirisi - June 27, 2019

Èèyàn méjìlá ti ṣèṣe lẹ́yìn tí ilé olókè mẹ́ta wó ní Èkó.

Ile oloke meta ti won n ko lowo ti wo ni Eko ni aato yii, eeyan mejila lo si ti sese. Gege bi iroyin se so, ile naa wo ni oru ojo Wednesday ni agbgbe Fagba.

Oloye ofisa Lagos State Emergency Management Agency, Olufemi Oke-Osanyintolu lo fi idi eri isele naa mule, o ni,

“Eyi ni lati so fun yin pe ile oloke meta kan spese wo ni K Farm, ni Fagba ni titi Iju. Won n ko ile naa lowo. Won ti ko awon ti won nibe kuro, won si ti n toju awon to sese. Eni kankan o ku. Awon ti isele naa kan ti wa lenu ise. Won ma wo ile naa sile patapata fun aabo awon ti n gbe ni adugbo naa. Won si ma se ayewo gbogbo awon ile ti o wa ni agbegbe naa.”

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Arábìnrin ti da omi gbóná lu ọmọ.

Owo olopaati tearabinrin kan ti o da omi gbona lu oju ara omobinrin kekere kan ti n gbe ni…