Home iroyin Àwọn gírádúétì ti kò ṣe NYSC lè jáde fún ipò gómìnà – Ilé ẹjọ́.

Àwọn gírádúétì ti kò ṣe NYSC lè jáde fún ipò gómìnà – Ilé ẹjọ́.

Ile ejo ni Abuja ti ni awon giridueti ti ko se National Youth Service Corp (NYSC) le jade fun ipo gomina.

Adajo M.A Mohammed so eyi nigba ti Senator Iyabo Anisulowo pe ejo fun Dapo Abiodun ti o jade fun ipo gomina. Abidoun nigba ti o da foomu CF001 pada fun INEC so fun pe oun o ni iwe eri NYSC. Abiodun o se NYSC, bi o tile je pe o jade ile iwe giga ni ofun 1986.

Anisulowo pe ejo pe ki won ma fun Abiodun ni aye lati dije fun ipo naa nitori ko si NYSC ti o pon dandan.

Ninu ejo ana June 26, Wale Ajayi, agbejoro fun gomina, ti ni ki ile ejo ya ejo naa si oto, niwon igba to je pe ko si akosile pe eeyan gbodo se NYSC ki o to le dije fun ipo oselu.

Adajo Mohammed si ni NYSC o fi aye sile lati ja enikeni ti ko ba se e kule. O ni won le ja eeyan kule gege bi iwe ofin se so ni Section 177 pe, “eeyan le dije fun ipo gomina ti o ba:
(a) je omo bibi ile Naijiria
(b) o ti pe omo odun marundinlogoji
(d) o je omo egbe, ti egeb re si setan lati ran an lowo.
(e) o ti ka iwe de ipo sekondiri.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Arábìnrin ti da omi gbóná lu ọmọ.

Owo olopaati tearabinrin kan ti o da omi gbona lu oju ara omobinrin kekere kan ti n gbe ni…