Home ÀRÒJINLẸ̀ “Àṣà wa ń fi àwọn olórí wa sí ipò tí wọ́n má fi j’alè àti hu ìwà ìbàjẹ́ “ – Prof Uno Igim.

“Àṣà wa ń fi àwọn olórí wa sí ipò tí wọ́n má fi j’alè àti hu ìwà ìbàjẹ́ “ – Prof Uno Igim.

Prof Uno Igim ti eka Public Administration ni yunifasiti ti Calabar, ti ni asa ile adulawo ti fi awon olori wa si ipo ti won ma fi jale ati hu iwa ibaje nitori won fe te awon eeyan won lorun.

Igim ni awon adulawo ma n beere nnkan pupo lowo awon olori ti won ba ti wa lori ipo nitori won fe te iwa imo tara eni won lorun ni ekan, bi o tile je pe owo ilu ni won ma ti owo bo.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Arábìnrin ti da omi gbóná lu ọmọ.

Owo olopaati tearabinrin kan ti o da omi gbona lu oju ara omobinrin kekere kan ti n gbe ni…