Home ÀRÒJINLẸ̀ Yunifásítì tí Ìpínlẹ̀ Èkó (LASU) ti dá akẹ́kọ̀ọ́ mẹ́ta dúró fún ẹ̀sùn ìfipábálòpọ̀ àti ẹgbẹ́ òkùnkùn.
ÀRÒJINLẸ̀ - iroyin - orisiirisii - Orisirisi - June 26, 2019

Yunifásítì tí Ìpínlẹ̀ Èkó (LASU) ti dá akẹ́kọ̀ọ́ mẹ́ta dúró fún ẹ̀sùn ìfipábálòpọ̀ àti ẹgbẹ́ òkùnkùn.

Won ti da akekoo meta duro ni yunifasiti ti ipinle eko fun esun ifipabalopo ayi egbe okunkun.

Ninu gbolohun ti agbenuso ile iwe naa so, Ademola Adekoya, o ni alakoso ile iwe naa, Prof. Olanrewaju Fagbohun ti fowo si pe ki won da awon akekoo naa duro. Awon akekoo naa bi gbolohun se so ni, Akanbi Oloyede, Tobilola Olutade ati Afeez Ogunbowale.

Won da Oloyede ati Olutade fun esun egbe okunkun, won si da Ogunbowale duro fun esun ifipabalopo.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Arábìnrin ti da omi gbóná lu ọmọ.

Owo olopaati tearabinrin kan ti o da omi gbona lu oju ara omobinrin kekere kan ti n gbe ni…